Wọn kò ní ṣe iṣẹ́ àṣedànù,wọn kò ní bímọ fún jamba;nítorí ọmọ ẹni tí OLUWA bukun ni wọn yóo jẹ́,àwọn ati àwọn ọmọ wọn.