Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 65:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò ní kọ́lé fún ẹlòmíràn gbé,wọn kò sì ní gbin ọgbà àjàrà fún ẹlòmíràn jẹ.Àwọn eniyan mi yóo pẹ́ láyé bí igi ìrókò,àwọn àyànfẹ́ mi yóo sì jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 65

Wo Aisaya 65:22 ni o tọ