ẹ̀yin tí ìlú yín kún fún ariwo, tí ẹ jẹ́ kìkì ìrúkèrúdò ati àríyá?Gbogbo àwọn tí ó kú ninu yín kò kú ikú idà,bẹ́ẹ̀ ni wọn kò kú lójú ogun.