Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 22:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ìjòyè ìlú yín parapọ̀ wọ́n sálọ,láì ta ọfà ni ọ̀tá mú wọn.Gbogbo àwọn tí wọn rí ni wọ́n mú,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti sá jìnnà.

Ka pipe ipin Aisaya 22

Wo Aisaya 22:3 ni o tọ