Wò ó nítorí náà, ènìyàn búburú fa ọfà Rẹ̀;wọn ti ọfà wọn sí ojú okùnláti tafà níbi òjìjìsí àyà ẹni ìdúró ṣinṣin.