Onídájọ́ 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Àwọn ọkùnrin Éfúráímù pe àwọn ológun wọn jáde, wọ́n sì rékọjá sí Sáfónì, wọ́n sì bi Jẹ́fítà pé, “Èéṣe tí o fi lọ bá àwọn ará Ámónì jagun láì ké sí wa láti bá ọ lọ? Àwa yóò ṣun ilé rẹ mọ́ ọ lórí.”