Nọ́ḿbà 18:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Àwọn ọmọ Léfì ní ó gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ tí ó wà nínú àgọ́ ìpàdé, wọn yóò sì jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn bí wọ́n bá kúrò láti ṣe é. Èyí ni ìlànà láéláé fún àwọn ìran tí ó ń bọ̀. Wọn kò ní gba ogún kankan láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.