Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 18:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kàkà bẹ́ẹ̀, mo fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí ogún wọn, ìdá kan nínú ìdá mẹ́wàá tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pèsè gẹ́gẹ́ bí ọrẹ sí Olúwa. Èyí ni mo wí nípa wọn: Wọn kò ní gba ogún kankan láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 18

Wo Nọ́ḿbà 18:24 ni o tọ