Nígbà náà ní gbogbo àwọn ọmọ ogun àti Jóhánánì ọmọkùnrin Káréà àti Jésánáyà omọkùnrin Hòsáyà àti kékeré títí dé orí ẹni ńlá wá.