Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 42:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sí ọ̀dọ̀ Jeremáyà wòlíì náà, wọ́n sì sọ fún un pé, “Jọ̀wọ́ gbọ́ ẹ̀bẹ̀ wa, kí o sì gbàdúrà sí Olúwa Ọlọ́run rẹ fún gbogbo ìyókù yìí. Nítorí gẹ́gẹ́ bi ìwọ ṣe rí i nísinsin yìí pé a pọ̀ níye nígbà kan rí; ṣùgbọ́n báyìí àwa díẹ̀ la sẹ́kù

Ka pipe ipin Jeremáyà 42

Wo Jeremáyà 42:2 ni o tọ