Ọlọ́run mi yóò kọ̀ wọ́n sílẹ̀nítorí pé wọn kò gbọ́ràn sí i;wọn yóò sì di alárìnkiri láàrin àwọn orílẹ̀ èdè.