Wọn yóò máa tẹ̀lé Olúwa;òun yóò bú ramúramù bí i kìnnìúnNígbà tó bá búàwọn ọmọ yóò wá ní ìwárìrì láti ìwọ̀ oòrùn.