Ékísódù 33:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Olúwa sọ fún Mósè pé, “Fi ìhín yìí sílẹ̀, ìwọ àti àwọn ènìyàn tí o mú gòkè láti Éjíbítì wá, kí ẹ sì gòkè lọ sí ilẹ̀ tí èmi ti pinnu ní ìbúra fún Ábúráhámù, Ísáákì àti Jákọ́bù wí pé, ‘Èmi yóò fi fún irú ọmọ rẹ.’