Ẹ gbinájẹ fún ìṣekúṣe láàrin igi óákùàti lábẹ́ gbogbo igi tí ń gbilẹ̀;ẹ fi àwọn ọmọ yín rúbọ nínú kòtò jínjìnàti lábẹ́ àwọn pàlàpálá òkúta.