Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 8:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki eyi ti a ti sọ lati ẹnu woli Isaiah wá le ṣẹ, pe, On tikararẹ̀ gbà ailera wa, o si nrù àrun wa.

Ka pipe ipin Mat 8

Wo Mat 8:17 ni o tọ