Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 6:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati iwọ ba ngbadura, máṣe dabi awọn agabagebe; nitori nwọn fẹ ati mã duro gbadura ni sinagogu ati ni igun ọ̀na ita, ki enia ki o ba le ri wọn. Lõtọ ni mo wi fun nyin, nwọn ti gbà ère wọn na.

Ka pipe ipin Mat 6

Wo Mat 6:5 ni o tọ