Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 5:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi oju ọtún rẹ ba mu ọ kọsẹ̀, yọ ọ jade, ki o si sọ ọ nù; o sá li ère fun ọ, ki ẹ̀ya ara rẹ kan ki o ṣegbé, jù ki a gbe gbogbo ara rẹ jù si iná ọrun apadi.

Ka pipe ipin Mat 5

Wo Mat 5:29 ni o tọ