Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 28:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ si yara lọ isọ fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, o ti jinde kuro ninu okú; wo o, ó ṣãju nyin lọ si Galili; nibẹ̀ li ẹnyin o gbé ri i: wo o, mo ti sọ fun nyin.

Ka pipe ipin Mat 28

Wo Mat 28:7 ni o tọ