Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 27:64 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina paṣẹ ki a kiyesi ibojì na daju titi yio fi di ijọ kẹta, ki awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ máṣe wá li oru, nwọn a si ji i gbé lọ, nwọn a si wi fun awọn enia pe, O jinde kuro ninu okú: bẹ̃ni ìṣina ìkẹhìn yio si buru jù ti iṣaju.

Ka pipe ipin Mat 27

Wo Mat 27:64 ni o tọ