Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 26:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o si ti nsọ lọwọ, wo o, Judasi, ọkan ninu awọn mejila de, ati ọ̀pọ enia pẹlu rẹ̀ ti awọn ti idà pẹlu ọgọ lati ọdọ awọn olori alufa ati awọn àgba awọn enia wá.

Ka pipe ipin Mat 26

Wo Mat 26:47 ni o tọ