Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 26:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. O SI ṣe, nigbati Jesu pari gbogbo ọ̀rọ wọnyi, o wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe,

2. Ẹnyin mọ̀ pe lẹhin ọjọ meji ni ajọ irekọja, a o si fi Ọmọ-enia le ni lọwọ, lati kàn a mọ agbelebu.

Ka pipe ipin Mat 26