Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 24:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si gburo ogun ati idagìri ogun: ẹ kiyesi i ki ẹnyin ki o máṣe jaiyà: nitori gbogbo nkan wọnyi ko le ṣe ki o ma ṣẹ, ṣugbọn opin ki iṣe isisiyi.

Ka pipe ipin Mat 24

Wo Mat 24:6 ni o tọ