Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 24:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojukanna lẹhin ipọnju ọjọ wọnni li õrùn yio ṣõkun, oṣupá kì yio si fi imọlẹ rẹ̀ hàn, awọn irawọ yio ti oju ọrun já silẹ, agbara oju ọrun li a o si mì titi:

Ka pipe ipin Mat 24

Wo Mat 24:29 ni o tọ