Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 20:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Jesu dahùn, o si wipe, Ẹnyin ko mọ̀ ohun ti ẹnyin mbère. Ẹnyin le mu ninu ago ti emi ó mu, ati ki a fi baptismu ti a o fi baptisi mi baptisi nyin? Nwọn wi fun u pe, Awa le ṣe e.

Ka pipe ipin Mat 20

Wo Mat 20:22 ni o tọ