Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 18:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbé ni fun aiye nitori ohun ikọsẹ̀! ohun ikọsẹ̀ ko le ṣe ki o ma de; ṣugbọn egbé ni fun oluwarẹ̀ na nipasẹ ẹniti ohun ikọsẹ̀ na ti wá!

Ka pipe ipin Mat 18

Wo Mat 18:7 ni o tọ