Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 14:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o di aṣalẹ awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ tọ̀ ọ wá, wipe, Ibi ijù li eyi, ọjọ si kọja tan: rán ijọ enia lọ, ki nwọn ki o le lọ si iletò lọ irà onjẹ fun ara wọn.

Ka pipe ipin Mat 14

Wo Mat 14:15 ni o tọ