Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dahùn wi fun wọn pe, Ẹnyin li a fifun lati mọ̀ ohun ijinlẹ ijọba ọrun, ṣugbọn awọn li a kò fifun.

Ka pipe ipin Mat 13

Wo Mat 13:11 ni o tọ