Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 12:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o lọ, o si mu ẹmi meje miran pẹlu ara rẹ̀, ti o buru jù on tikararẹ̀ lọ; nwọn bọ si inu rẹ̀, nwọn si ngbé ibẹ̀; igbẹhin ọkunrin na si buru jù iṣaju rẹ̀ lọ. Gẹgẹ bẹ̃ni yio ri fun iran buburu yi pẹlu.

Ka pipe ipin Mat 12

Wo Mat 12:45 ni o tọ