Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 12:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọbabirin gusù yio dide pẹlu iran yi li ọjọ idajọ, yio si da a lẹbi: nitori o ti ikangun aiye wá igbọ́ ọgbọ́n Solomoni; si wò o, ẹniti o pọ̀ ju Solomoni lọ mbẹ nihinyi.

Ka pipe ipin Mat 12

Wo Mat 12:42 ni o tọ