Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

LAKOKÒ na ni Jesu là ãrin oko ọkà lọ li ọjọ isimi; ebi si npa awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, nwọn si bẹ̀rẹ si ima ya ipẹ́ ọkà, nwọn si njẹ.

Ka pipe ipin Mat 12

Wo Mat 12:1 ni o tọ