Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 9:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si joko, o si pè awọn mejila na, o si wi fun wọn pe, Bi ẹnikẹni ba nfẹ ṣe ẹni iwaju, on na ni yio ṣe ẹni ikẹhin gbogbo wọn, ati iranṣẹ gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Mak 9

Wo Mak 9:35 ni o tọ