Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 9:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dahùn o si wi fun wọn pe, Lõtọ, ni Elijah yio tètekọ, de, yio si mu nkan gbogbo pada si ipò; ati gẹgẹ bi a ti kọwe rẹ̀ nipa ti Ọmọ-enia pe, ko le ṣaima jìya ohun pipọ, ati pe a o si kọ̀ ọ silẹ.

Ka pipe ipin Mak 9

Wo Mak 9:12 ni o tọ