Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 6:48 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ri nwọn nṣiṣẹ ni wiwà ọkọ̀; nitoriti afẹfẹ ṣe ọwọ òdi si wọn: nigbati o si di ìwọn iṣọ kẹrin oru, o tọ̀ wọn wá, o nrìn lori okun, on si nfẹ ré wọn kọja.

Ka pipe ipin Mak 6

Wo Mak 6:48 ni o tọ