Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 6:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia si ri wọn nigbati nwọn nlọ, ọ̀pọlọpọ si mọ̀ ọ, nwọn si sare ba ti ẹsẹ lọ sibẹ̀ lati ilu nla gbogbo wá, nwọn si ṣiwaju wọn, nwọn si jùmọ wá sọdọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Mak 6

Wo Mak 6:33 ni o tọ