Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 6:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Herodu bẹ̀ru Johanu, o si mọ̀ ọ li olõtọ enia ati ẹni mimọ́, o si ntọju rẹ̀; nigbati o gbọrọ rẹ̀, o ṣe ohun pipọ, o si fi ayọ̀ gbọrọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Mak 6

Wo Mak 6:20 ni o tọ