Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 6:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati o si di ọjọ isimi, o bẹ̀rẹ si ikọni ninu sinagogu; ẹnu si yà awọn enia pipọ ti o gbọ́, nwọn wipe, Nibo li ọkunrin yi gbé ti ri nkan wọnyi? irú ọgbọ́n kili eyi ti a fifun u, ti irú iṣẹ agbara bayi nti ọwọ́ rẹ̀ ṣe?

Ka pipe ipin Mak 6

Wo Mak 6:2 ni o tọ