Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 5:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn obinrin na ni ibẹ̀ru ati iwarìri, bi o ti mọ̀ ohun ti a ṣe lara on, o wá, o si wolẹ niwaju rẹ̀, o si sọ gbogbo otitọ fun u.

Ka pipe ipin Mak 5

Wo Mak 5:33 ni o tọ