Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 5:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti oju rẹ̀ si ri ohun pipọ lọdọ ọ̀pọ awọn oniṣegun, ti o si ti ná ohun gbogbo ti o ni tan, ti kò si sàn rara, ṣugbọn kàka bẹ̃ o npọ̀ siwaju.

Ka pipe ipin Mak 5

Wo Mak 5:26 ni o tọ