Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 3:34-35 Yorùbá Bibeli (YCE)

34. O si wò gbogbo awọn ti o joko lọdọ rẹ̀ yiká, o si wipe, Wò iya mi ati awọn arakunrin mi:

35. Nitori ẹnikẹni ti o ba ṣe ifẹ Ọlọrun, on na li arakunrin mi, ati arabinrin mi, ati iya mi.

Ka pipe ipin Mak 3