Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi Jesu ti nkọja lọ lãrin oko ọkà li ọjọ isimi; awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ bẹ̀rẹ si ima ya ipẹ́ ọkà bi nwọn ti nlọ.

Ka pipe ipin Mak 2

Wo Mak 2:23 ni o tọ