Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 16:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si wọ̀ inu ibojì na, nwọn ri ọmọkunrin kan joko li apa ọtún, ti o wọ̀ agbada funfun; ẹ̀ru si ba wọn.

Ka pipe ipin Mak 16

Wo Mak 16:5 ni o tọ