Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 15:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati balogun ọrún, ti o duro niha ọdọ rẹ̀ ri ti o kigbe soke bayi, ti o si jọwọ ẹmi rẹ̀ lọwọ, o wipe, Lõtọ Ọmọ Ọlọrun li ọkunrin yi iṣe.

Ka pipe ipin Mak 15

Wo Mak 15:39 ni o tọ