Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 15:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ATI lojukanna li owurọ, awọn olori alufa jọ gbìmọ pẹlu awọn alàgba, ati awọn akọwe, ati gbogbo ajọ ìgbimọ, nwọn si dè Jesu, nwọn si mu u lọ, nwọn si fi i le Pilatu lọwọ.

Ka pipe ipin Mak 15

Wo Mak 15:1 ni o tọ