Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 14:72 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lojukanna akukọ si kọ lẹrinkeji. Peteru si ranti ọrọ ti Jesu wi fun u pe, Ki akukọ ki o to kọ lẹrinmeji, iwo o sẹ́ mi lẹrinmẹta. Nigbati o si rò o, o sọkun.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:72 ni o tọ