Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 14:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li ọjọ kini ajọ aiwukara, nigbati nwọn npa ẹran irekọja, awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si wi fun u pe, Nibo ni iwọ nfẹ ki a lọ ipèse silẹ, ki iwọ́ ki o le jẹ irekọja.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:12 ni o tọ