Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 13:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Ọmọ-enia dabi ọkunrin kan ti o lọ si àjo ti o jìna rére, ẹniti o fi ile rẹ̀ silẹ, ti o si fi aṣẹ fun awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀, ati iṣẹ olukuluku fun u, ti o si fi aṣẹ fun oluṣọna ki o mã ṣọna.

Ka pipe ipin Mak 13

Wo Mak 13:34 ni o tọ