Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 12:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si pè awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ sọdọ rẹ̀, o si wi fun wọn pe, Lõtọ ni mo wi fun nyin pe, Talakà opó yi sọ sinu apoti iṣura jù gbogbo awọn ti o sọ sinu rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:43 ni o tọ