Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 12:41 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesu si joko kọjusi apoti iṣura, o si nwò bi ijọ enia ti nsọ owo sinu apoti iṣura: ọ̀pọ awọn ọlọrọ̀ si sọ pipọ si i.

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:41 ni o tọ