Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 12:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati Jesu ri i pe o fi òye dahùn, o wi fun u pe, Iwọ kò jìna si ijọba Ọlọrun. Lẹhin eyini, kò si ẹnikan ti o jẹ bi i lẽre ohunkan mọ́.

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:34 ni o tọ