Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mak 12:32 Yorùbá Bibeli (YCE)

Akọwe na si wi fun u pe, Olukọni, o dara, otitọ li o sọ pe Ọlọrun kan ni mbẹ; ko si si omiran bikoṣe on:

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:32 ni o tọ